Bahia - Angélique Kidjo

歌手:Angélique Kidjo · 专辑:Black Ivory Soul · 发行:2002-03-19
歌曲信息
歌曲名:Bahia
歌手:Angélique Kidjo
所属专辑:Black Ivory Soul
发行时间:2002-03-19
介绍:《Bahia - Angélique Kidjo》Angélique Kidjo & Angélique Kidjo演唱的歌曲,由未知作词、未知作曲。 如果你觉得好听,欢迎分享给朋友一起看看歌词,一起支持歌手!
Bahia - Angélique Kidjo 文本歌词
Bahia - Angelique Kidjo
Aburo orè ni gbogbowa ewa ka lolé
Aburo ibi kan ni wao kamura si ifè
Ouidah ni ilé ti bahia
Ti émin mon wa ri yin lénin o
Bahia bahia bahia bahia bahia bahia
Ilé ti babawa djinan awa fè lolé
Bahia ilou ti awa lenin okpè gan si ilé
Ogun ti awon agbalagba shé kalè foun wa o
Logbé wa lo si bahia gbé gbogbowa kpo
Bahia bahia bahia bahia bahia bahia
Odjo ikadé wa m'bowa o ti ale rira wa
Ewa ka moura foun odjo yin ninou oyaya
Oluwa foun wa ni ayé edjè ka du kpè
Bahia kpa gbogbowa kpo iréti wa lonan
Aburo orè ni gbogbowa ewa ka lolé
Aburo ibi kan ni wao kamura si ifè
Ouidah ni ilé ti bahia
Ti émin mon wa ri yin lénin o
Oré ifé ayé ilé oré ifé ayé ilé
Aburo orè ni gbogbowa ewa ka lolé
Aburo ibi kan ni wao kamura si ifè
Ouidah ni ilé ti bahia
Ti émin mon wa ri yin lénin o
Oré ifé ayé ilé oré ifé ayé ilé
Bahia - Angélique Kidjo LRC歌词
当前歌曲暂无LRC歌词
其他歌词